Ẹ́kísódù 4:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Mósè sọ gbogbo ọ̀rọ̀ Jèhófà, ẹni tó rán an, fún Áárónì,+ ó sì sọ fún un nípa gbogbo iṣẹ́ àmì tó pa láṣẹ pé kó ṣe.+
28 Mósè sọ gbogbo ọ̀rọ̀ Jèhófà, ẹni tó rán an, fún Áárónì,+ ó sì sọ fún un nípa gbogbo iṣẹ́ àmì tó pa láṣẹ pé kó ṣe.+