-
Ẹ́kísódù 40:30, 31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Lẹ́yìn náà, ó gbé bàsíà sí àárín àgọ́ ìpàdé àti pẹpẹ, ó sì bu omi sínú rẹ̀ fún wíwẹ̀.+ 31 Mósè àti Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ wẹ ọwọ́ àti ẹsẹ̀ wọn níbẹ̀.
-