-
Ẹ́kísódù 29:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Ọjọ́ méje ni kí o fi ṣe ètùtù fún pẹpẹ náà, kí o sì sọ ọ́ di mímọ́ kó lè di pẹpẹ mímọ́ jù lọ.+ Ẹnikẹ́ni tó bá fara kan pẹpẹ náà ti gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́.
-