-
Ẹ́kísódù 38:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Òhólíábù+ ọmọ Áhísámákì látinú ẹ̀yà Dánì sì wà pẹ̀lú rẹ̀, ó jẹ́ oníṣẹ́ ọnà, ó máa ń kóṣẹ́ sí aṣọ, ó sì máa ń hun aṣọ pẹ̀lú fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa.
-