Jẹ́nẹ́sísì 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nígbà tó fi máa di ọjọ́ keje, Ọlọ́run ti parí iṣẹ́ tó ti ń ṣe,* ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í sinmi ní ọjọ́ keje lẹ́yìn gbogbo iṣẹ́ tó ti ń ṣe.*+
2 Nígbà tó fi máa di ọjọ́ keje, Ọlọ́run ti parí iṣẹ́ tó ti ń ṣe,* ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í sinmi ní ọjọ́ keje lẹ́yìn gbogbo iṣẹ́ tó ti ń ṣe.*+