1 Kọ́ríńtì 10:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ má ṣe di abọ̀rìṣà, bí àwọn kan nínú wọn ti ṣe; gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Àwọn èèyàn náà jókòó láti jẹ àti láti mu. Wọ́n sì dìde láti gbádùn ara wọn.”+
7 Bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ má ṣe di abọ̀rìṣà, bí àwọn kan nínú wọn ti ṣe; gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Àwọn èèyàn náà jókòó láti jẹ àti láti mu. Wọ́n sì dìde láti gbádùn ara wọn.”+