Ẹ́kísódù 40:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Lẹ́yìn náà, ó mú Ẹ̀rí,+ ó sì fi sínú Àpótí náà.+ Ó ki àwọn ọ̀pá+ sí ẹ̀gbẹ́ Àpótí náà, ó sì fi ìbòrí+ bo Àpótí náà.+ Diutarónómì 5:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Àwọn àṣẹ* yìí ni Jèhófà pa fún gbogbo ìjọ yín lórí òkè náà, látinú iná àti ìkùukùu* àti ìṣúdùdù tó kàmàmà+ pẹ̀lú ohùn tó dún ketekete, kò sì fi ohunkóhun kún un; ó wá kọ wọ́n sórí wàláà òkúta méjì, ó sì kó o fún mi.+
20 Lẹ́yìn náà, ó mú Ẹ̀rí,+ ó sì fi sínú Àpótí náà.+ Ó ki àwọn ọ̀pá+ sí ẹ̀gbẹ́ Àpótí náà, ó sì fi ìbòrí+ bo Àpótí náà.+
22 “Àwọn àṣẹ* yìí ni Jèhófà pa fún gbogbo ìjọ yín lórí òkè náà, látinú iná àti ìkùukùu* àti ìṣúdùdù tó kàmàmà+ pẹ̀lú ohùn tó dún ketekete, kò sì fi ohunkóhun kún un; ó wá kọ wọ́n sórí wàláà òkúta méjì, ó sì kó o fún mi.+