Ẹ́kísódù 31:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Gbàrà tó bá a sọ̀rọ̀ tán lórí Òkè Sínáì, ó fún Mósè ní wàláà Ẹ̀rí méjì,+ àwọn wàláà òkúta tí ìka Ọlọ́run+ kọ̀wé sí. Diutarónómì 9:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jèhófà wá fún mi ní àwọn wàláà òkúta méjì tí ìka Ọlọ́run kọ̀wé sí, gbogbo ọ̀rọ̀ tí Jèhófà bá yín sọ ní òkè náà látinú iná ní ọjọ́ tí ẹ pé jọ* sì wà lára rẹ̀.+
18 Gbàrà tó bá a sọ̀rọ̀ tán lórí Òkè Sínáì, ó fún Mósè ní wàláà Ẹ̀rí méjì,+ àwọn wàláà òkúta tí ìka Ọlọ́run+ kọ̀wé sí.
10 Jèhófà wá fún mi ní àwọn wàláà òkúta méjì tí ìka Ọlọ́run kọ̀wé sí, gbogbo ọ̀rọ̀ tí Jèhófà bá yín sọ ní òkè náà látinú iná ní ọjọ́ tí ẹ pé jọ* sì wà lára rẹ̀.+