-
Ẹ́kísódù 7:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “Tí Fáráò bá sọ fún yín pé, ‘Ẹ ṣe iṣẹ́ ìyanu,’ kí o sọ fún Áárónì pé, ‘Mú ọ̀pá rẹ, kí o sì jù ú sílẹ̀ níwájú Fáráò.’ Ọ̀pá náà yóò di ejò ńlá.”+
-