Ẹ́kísódù 23:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín+ kó lè dáàbò bò yín lójú ọ̀nà, kó sì mú yín wá síbi tí mo ti ṣètò sílẹ̀.+ Ẹ́kísódù 32:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Máa lọ báyìí, darí àwọn èèyàn náà lọ síbi tí mo bá ọ sọ. Wò ó! Áńgẹ́lì mi yóò ṣáájú rẹ.+ Lọ́jọ́ tí mo bá sì fẹ́ ṣèdájọ́, èmi yóò fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn jẹ wọ́n.”
20 “Màá rán áńgẹ́lì kan ṣáájú yín+ kó lè dáàbò bò yín lójú ọ̀nà, kó sì mú yín wá síbi tí mo ti ṣètò sílẹ̀.+
34 Máa lọ báyìí, darí àwọn èèyàn náà lọ síbi tí mo bá ọ sọ. Wò ó! Áńgẹ́lì mi yóò ṣáájú rẹ.+ Lọ́jọ́ tí mo bá sì fẹ́ ṣèdájọ́, èmi yóò fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn jẹ wọ́n.”