Jóṣúà 21:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Bákan náà, Jèhófà fún wọn ní ìsinmi ní gbogbo àyíká wọn, bó ṣe búra fún àwọn baba ńlá wọn,+ ìkankan nínú àwọn ọ̀tá wọn ò sì lè dojú kọ wọ́n.+ Jèhófà fi gbogbo ọ̀tá wọn lé wọn lọ́wọ́.+ Jóṣúà 23:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Lẹ́yìn ọ̀pọ̀ ọjọ́ tí Jèhófà ti fún Ísírẹ́lì ní ìsinmi+ lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá tó yí wọn ká, tí Jóṣúà ti darúgbó, tó sì ti lọ́jọ́ lórí,+
44 Bákan náà, Jèhófà fún wọn ní ìsinmi ní gbogbo àyíká wọn, bó ṣe búra fún àwọn baba ńlá wọn,+ ìkankan nínú àwọn ọ̀tá wọn ò sì lè dojú kọ wọ́n.+ Jèhófà fi gbogbo ọ̀tá wọn lé wọn lọ́wọ́.+
23 Lẹ́yìn ọ̀pọ̀ ọjọ́ tí Jèhófà ti fún Ísírẹ́lì ní ìsinmi+ lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá tó yí wọn ká, tí Jóṣúà ti darúgbó, tó sì ti lọ́jọ́ lórí,+