Diutarónómì 10:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Ìgbà yẹn ni Jèhófà sọ fún mi pé, ‘Kí ìwọ fúnra rẹ gbẹ́ wàláà òkúta méjì, irú ti àkọ́kọ́,+ kí o sì wá bá mi lórí òkè náà; kí ìwọ fúnra rẹ tún fi pákó ṣe àpótí.*
10 “Ìgbà yẹn ni Jèhófà sọ fún mi pé, ‘Kí ìwọ fúnra rẹ gbẹ́ wàláà òkúta méjì, irú ti àkọ́kọ́,+ kí o sì wá bá mi lórí òkè náà; kí ìwọ fúnra rẹ tún fi pákó ṣe àpótí.*