Diutarónómì 9:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jèhófà wá fún mi ní àwọn wàláà òkúta méjì tí ìka Ọlọ́run kọ̀wé sí, gbogbo ọ̀rọ̀ tí Jèhófà bá yín sọ ní òkè náà látinú iná ní ọjọ́ tí ẹ pé jọ* sì wà lára rẹ̀.+
10 Jèhófà wá fún mi ní àwọn wàláà òkúta méjì tí ìka Ọlọ́run kọ̀wé sí, gbogbo ọ̀rọ̀ tí Jèhófà bá yín sọ ní òkè náà látinú iná ní ọjọ́ tí ẹ pé jọ* sì wà lára rẹ̀.+