-
Jẹ́nẹ́sísì 17:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Tí ọkùnrin èyíkéyìí ò bá dá adọ̀dọ́ rẹ̀, kí wọ́n pa ẹni* náà, kí wọ́n lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀. Ó ti da májẹ̀mú mi.”
-