Ẹ́kísódù 32:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Wọ́n ti yára kúrò ní ọ̀nà tí mo pa láṣẹ fún wọn pé kí wọ́n máa rìn.+ Wọ́n ti ṣe ère* ọmọ màlúù fún ara wọn, wọ́n ń tẹrí ba fún un, wọ́n sì ń rúbọ sí i, wọ́n ń sọ pé, ‘Ìwọ Ísírẹ́lì, Ọlọ́run rẹ nìyí, òun ló mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.’” Léfítíkù 19:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ má ṣe yíjú sí àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí+ tàbí kí ẹ fi irin rọ àwọn ọlọ́run+ fún ara yín. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.
8 Wọ́n ti yára kúrò ní ọ̀nà tí mo pa láṣẹ fún wọn pé kí wọ́n máa rìn.+ Wọ́n ti ṣe ère* ọmọ màlúù fún ara wọn, wọ́n ń tẹrí ba fún un, wọ́n sì ń rúbọ sí i, wọ́n ń sọ pé, ‘Ìwọ Ísírẹ́lì, Ọlọ́run rẹ nìyí, òun ló mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.’”
4 Ẹ má ṣe yíjú sí àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí+ tàbí kí ẹ fi irin rọ àwọn ọlọ́run+ fún ara yín. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.