Ẹ́kísódù 22:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ohun tí wàá ṣe sí akọ màlúù àti àgùntàn rẹ nìyí:+ Kí ó wà pẹ̀lú ìyá rẹ̀ fún ọjọ́ méje. Tó bá di ọjọ́ kẹjọ, kí o mú un wá fún mi.+
30 Ohun tí wàá ṣe sí akọ màlúù àti àgùntàn rẹ nìyí:+ Kí ó wà pẹ̀lú ìyá rẹ̀ fún ọjọ́ méje. Tó bá di ọjọ́ kẹjọ, kí o mú un wá fún mi.+