-
Ẹ́kísódù 23:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “O ò gbọ́dọ̀ fi ẹ̀jẹ̀ rúbọ sí mi pa pọ̀ pẹ̀lú ohun tó ní ìwúkàrà. Ọ̀rá tí o bá fi rúbọ níbi àwọn àjọyọ̀ mi ò sì gbọ́dọ̀ ṣẹ́ kù di àárọ̀ ọjọ́ kejì.
-