ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 24:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Mósè wá kọ gbogbo ọ̀rọ̀ Jèhófà sílẹ̀.+ Ó dìde ní àárọ̀ kùtù, ó sì mọ pẹpẹ kan sísàlẹ̀ òkè náà àti òpó méjìlá (12) tó dúró fún ẹ̀yà méjìlá (12) Ísírẹ́lì.

  • Diutarónómì 31:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Mósè wá kọ Òfin yìí,+ ó sì fún àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì, tí wọ́n ń gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà àti gbogbo àgbààgbà Ísírẹ́lì.

  • Diutarónómì 31:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 nígbà tí gbogbo Ísírẹ́lì bá wá síwájú Jèhófà+ Ọlọ́run rẹ ní ibi tó yàn, kí ẹ ka Òfin yìí sí gbogbo Ísírẹ́lì létí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́