-
Diutarónómì 9:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Mo wá wólẹ̀ níwájú Jèhófà, bíi ti àkọ́kọ́, fún ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru. Mi ò jẹ, mi ò sì mu,+ torí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí ẹ dá bí ẹ ṣe ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà, tí ẹ sì ń múnú bí i.
-