-
Léfítíkù 22:18-20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “Sọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ àti gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Tí ọmọ Ísírẹ́lì kan tàbí àjèjì kan ní Ísírẹ́lì bá mú ẹran ẹbọ sísun+ wá fún Jèhófà kó lè fi san ẹ̀jẹ́ rẹ̀ tàbí kó lè fi ṣe ọrẹ àtinúwá,+ 19 akọ ẹran tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá+ ni kó mú wá látinú ọ̀wọ́ ẹran, àwọn ọmọ àgbò tàbí àwọn ewúrẹ́ kó lè rí ìtẹ́wọ́gbà. 20 Ẹ ò gbọ́dọ̀ mú ohunkóhun tó ní àbùkù+ wá, torí kò ní mú kí ẹ rí ìtẹ́wọ́gbà.
-