-
Ẹ́kísódù 32:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Ní ọjọ́ kejì, Mósè sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ̀ṣẹ̀ ńlá lẹ dá, màá sì gòkè tọ Jèhófà lọ báyìí, kí n wò ó bóyá mo lè bá yín wá nǹkan ṣe sí ẹ̀ṣẹ̀ tí ẹ dá.”+
-