ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 12:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Tí ọjọ́ ìwẹ̀mọ́ rẹ̀ fún ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin bá pé, kó mú ọmọ àgbò ọlọ́dún kan wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé fún àlùfáà láti fi rú ẹbọ sísun,+ kó sì mú ọmọ ẹyẹlé tàbí oriri kan wá láti fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.

  • Léfítíkù 22:18-20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 “Sọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ àti gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Tí ọmọ Ísírẹ́lì kan tàbí àjèjì kan ní Ísírẹ́lì bá mú ẹran ẹbọ sísun+ wá fún Jèhófà kó lè fi san ẹ̀jẹ́ rẹ̀ tàbí kó lè fi ṣe ọrẹ àtinúwá,+ 19 akọ ẹran tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá+ ni kó mú wá látinú ọ̀wọ́ ẹran, àwọn ọmọ àgbò tàbí àwọn ewúrẹ́ kó lè rí ìtẹ́wọ́gbà. 20 Ẹ ò gbọ́dọ̀ mú ohunkóhun tó ní àbùkù+ wá, torí kò ní mú kí ẹ rí ìtẹ́wọ́gbà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́