Ẹ́kísódù 28:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Kí o tún fi aṣọ ọ̀gbọ̀ ṣe ṣòkòtò péńpé* fún wọn kó lè bo ìhòòhò wọn.+ Kó gùn láti ìbàdí dé itan. Ẹ́kísódù 39:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe aṣọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, ẹni tó ń hun aṣọ ló ṣe é,+ 28 wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe láwàní+ àti aṣọ tí wọ́n ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ tí wọ́n máa wé sórí,+ wọ́n sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa ṣe àwọn ṣòkòtò péńpé,*+
27 Wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe aṣọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, ẹni tó ń hun aṣọ ló ṣe é,+ 28 wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe láwàní+ àti aṣọ tí wọ́n ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ tí wọ́n máa wé sórí,+ wọ́n sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa ṣe àwọn ṣòkòtò péńpé,*+