Ẹ́kísódù 30:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Kí o fi òróró yan Áárónì+ àti àwọn ọmọ rẹ̀,+ kí o sì sọ wọ́n di mímọ́ kí wọ́n lè di àlùfáà mi.+ Hébérù 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí gbogbo àlùfáà àgbà tí a mú láàárín àwọn èèyàn ni a yàn nítorí wọn láti bójú tó àwọn ohun tó jẹ mọ́ Ọlọ́run,+ kó lè fi àwọn ọrẹ àti ẹbọ rúbọ nítorí ẹ̀ṣẹ̀.+
5 Torí gbogbo àlùfáà àgbà tí a mú láàárín àwọn èèyàn ni a yàn nítorí wọn láti bójú tó àwọn ohun tó jẹ mọ́ Ọlọ́run,+ kó lè fi àwọn ọrẹ àti ẹbọ rúbọ nítorí ẹ̀ṣẹ̀.+