Léfítíkù 17:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí ẹ̀jẹ̀ ni ẹ̀mí* gbogbo onírúurú ẹran, torí pé ẹ̀mí* wà nínú ẹ̀jẹ̀ náà. Ìdí nìyẹn tí mo fi sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: “Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ̀jẹ̀ ẹran èyíkéyìí, torí ẹ̀jẹ̀ ni ẹ̀mí* gbogbo onírúurú ẹran. Kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá jẹ ẹ́.”+
14 Torí ẹ̀jẹ̀ ni ẹ̀mí* gbogbo onírúurú ẹran, torí pé ẹ̀mí* wà nínú ẹ̀jẹ̀ náà. Ìdí nìyẹn tí mo fi sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: “Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ̀jẹ̀ ẹran èyíkéyìí, torí ẹ̀jẹ̀ ni ẹ̀mí* gbogbo onírúurú ẹran. Kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá jẹ ẹ́.”+