Léfítíkù 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kó fi lára ẹbọ ìrẹ́pọ̀ náà ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà:+ ọ̀rá+ tó bo ìfun, gbogbo ọ̀rá tó yí ìfun ká