Léfítíkù 8:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Mósè tún mú igẹ̀, ó sì fì í síwá-sẹ́yìn bí ọrẹ fífì níwájú Jèhófà.+ Ó di ìpín Mósè látinú àgbò àfiyanni, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún un.+
29 Mósè tún mú igẹ̀, ó sì fì í síwá-sẹ́yìn bí ọrẹ fífì níwájú Jèhófà.+ Ó di ìpín Mósè látinú àgbò àfiyanni, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún un.+