-
Ẹ́kísódù 39:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 àwọn aṣọ tí wọ́n hun dáadáa láti máa fi ṣiṣẹ́ ní ibi mímọ́, aṣọ mímọ́ ti àlùfáà Áárónì+ àti àwọn aṣọ tí àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ máa fi ṣiṣẹ́ àlùfáà.
-