Ẹ́kísódù 28:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 “Kí o fi ògidì wúrà ṣe irin pẹlẹbẹ tó ń dán, kí o sì fín ọ̀rọ̀ yìí sára rẹ̀ bí ẹni fín èdìdì, pé: ‘Ìjẹ́mímọ́ jẹ́ ti Jèhófà.’+ Ẹ́kísódù 39:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Níkẹyìn, wọ́n fi ògidì wúrà ṣe irin pẹlẹbẹ tó ń dán, tó jẹ́ àmì mímọ́ ti ìyàsímímọ́,* wọ́n sì fín ọ̀rọ̀ sára rẹ̀ bí ẹni fín èdìdì, pé: “Ìjẹ́mímọ́ jẹ́ ti Jèhófà.”+
36 “Kí o fi ògidì wúrà ṣe irin pẹlẹbẹ tó ń dán, kí o sì fín ọ̀rọ̀ yìí sára rẹ̀ bí ẹni fín èdìdì, pé: ‘Ìjẹ́mímọ́ jẹ́ ti Jèhófà.’+
30 Níkẹyìn, wọ́n fi ògidì wúrà ṣe irin pẹlẹbẹ tó ń dán, tó jẹ́ àmì mímọ́ ti ìyàsímímọ́,* wọ́n sì fín ọ̀rọ̀ sára rẹ̀ bí ẹni fín èdìdì, pé: “Ìjẹ́mímọ́ jẹ́ ti Jèhófà.”+