-
Ẹ́kísódù 30:26-28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 “Kí o ta òróró náà sí àgọ́ ìpàdé+ àti àpótí Ẹ̀rí, 27 pẹ̀lú tábìlì àti gbogbo ohun èlò rẹ̀, ọ̀pá fìtílà àti àwọn ohun èlò rẹ̀, pẹpẹ tùràrí, 28 pẹpẹ ẹbọ sísun àti gbogbo ohun èlò rẹ̀, pẹ̀lú bàsíà àti ẹsẹ̀ rẹ̀.
-