Hébérù 9:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Bákan náà, ó fi ẹ̀jẹ̀ náà wọ́n àgọ́ àti gbogbo ohun tí wọ́n ń lò fún iṣẹ́ ìsìn mímọ́.*+ 22 Àní bí Òfin ṣe sọ, ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé gbogbo nǹkan ni wọ́n ń fi ẹ̀jẹ̀ wẹ̀ mọ́,+ ìdáríjì kankan ò sì lè wáyé àfi tí a bá tú ẹ̀jẹ̀ jáde.+
21 Bákan náà, ó fi ẹ̀jẹ̀ náà wọ́n àgọ́ àti gbogbo ohun tí wọ́n ń lò fún iṣẹ́ ìsìn mímọ́.*+ 22 Àní bí Òfin ṣe sọ, ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé gbogbo nǹkan ni wọ́n ń fi ẹ̀jẹ̀ wẹ̀ mọ́,+ ìdáríjì kankan ò sì lè wáyé àfi tí a bá tú ẹ̀jẹ̀ jáde.+