-
Ẹ́kísódù 29:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Bí èyíkéyìí nínú ẹran tí o fi rú ẹbọ ìyannisípò àti búrẹ́dì náà bá ṣẹ́ kù di àárọ̀, kí o fi iná sun ohun tó ṣẹ́ kù.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ́, torí ohun mímọ́ ni.
-