-
2 Sámúẹ́lì 6:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Nígbà tí Dáfídì parí rírú àwọn ẹbọ sísun àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀ náà, ó fi orúkọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun súre fún àwọn èèyàn náà.
-
-
2 Kíróníkà 6:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Lẹ́yìn náà, ọba yíjú pa dà, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í súre fún gbogbo ìjọ Ísírẹ́lì, bí gbogbo ìjọ Ísírẹ́lì ṣe wà ní ìdúró.+
-