-
Léfítíkù 9:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Àmọ́ kí o sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Ẹ mú akọ ewúrẹ́ kan láti fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ àti ọmọ màlúù kan àti ọmọ àgbò kan, kí ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ ọlọ́dún kan tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá, kí ẹ fi rú ẹbọ sísun,
-
-
Léfítíkù 9:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Lẹ́yìn náà, ó mú ọrẹ àwọn èèyàn náà wá, ó mú ewúrẹ́ tó fẹ́ fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ fún àwọn èèyàn náà, ó sì pa á, ó sì fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ bíi ti àkọ́kọ́.
-