-
Ìsíkíẹ́lì 43:23, 24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 “‘Tí o bá ti wẹ̀ ẹ́ mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ tán, kí o mú akọ ọmọ màlúù kan látinú agbo ẹran, èyí tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá àti àgbò kan látinú ọ̀wọ́ ẹran, èyí tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá, kí o sì fi wọ́n rúbọ. 24 Kí o gbé wọn wá síwájú Jèhófà, kí àwọn àlùfáà da iyọ̀ sí wọn lára,+ kí wọ́n sì fi wọ́n rú odindi ẹbọ sísun sí Jèhófà.
-