Àìsáyà 66:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àwọn tó ń sọ ara wọn di mímọ́, tí wọ́n sì ń wẹ ara wọn láti wọnú àwọn ọgbà,*+ tí wọ́n ń tẹ̀ lé ẹni tó wà ní àárín, àwọn tó ń jẹ ẹran ẹlẹ́dẹ̀,+ àwọn ohun ìríra àti eku,+ gbogbo wọn jọ máa wá sí òpin wọn,” ni Jèhófà wí.
17 Àwọn tó ń sọ ara wọn di mímọ́, tí wọ́n sì ń wẹ ara wọn láti wọnú àwọn ọgbà,*+ tí wọ́n ń tẹ̀ lé ẹni tó wà ní àárín, àwọn tó ń jẹ ẹran ẹlẹ́dẹ̀,+ àwọn ohun ìríra àti eku,+ gbogbo wọn jọ máa wá sí òpin wọn,” ni Jèhófà wí.