-
Nọ́ńbà 6:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 “‘Èyí ni òfin nípa Násírì: Tí ọjọ́ tó fi jẹ́ Násírì+ bá pé, kí ẹ mú un wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé. 14 Ibẹ̀ ni kó mú ọrẹ rẹ̀ tó fẹ́ fún Jèhófà wá: ọmọ àgbò ọlọ́dún kan tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá láti fi rú ẹbọ sísun,+ abo ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá láti fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀,+ àgbò kan tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá láti fi rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀,+
-