-
Léfítíkù 6:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Kó sì mú àgbò tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá wá fún àlùfáà láti fi rú ẹbọ ẹ̀bi fún Jèhófà, kí àgbò náà tó iye tí wọ́n dá lé e, láti fi rú ẹbọ ẹ̀bi.+
-