ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 6:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 “‘Èyí ni òfin nípa Násírì: Tí ọjọ́ tó fi jẹ́ Násírì+ bá pé, kí ẹ mú un wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé. 14 Ibẹ̀ ni kó mú ọrẹ rẹ̀ tó fẹ́ fún Jèhófà wá: ọmọ àgbò ọlọ́dún kan tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá láti fi rú ẹbọ sísun,+ abo ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá láti fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀,+ àgbò kan tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá láti fi rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́