-
Léfítíkù 14:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àmọ́ kó mú ààyè ẹyẹ kejì pẹ̀lú igi kédárì, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti ewéko hísópù, kó sì kì wọ́n pa pọ̀ bọnú ẹ̀jẹ̀ ẹyẹ tí wọ́n pa lórí omi tó ń ṣàn. 7 Kó wá wọ́n ọn lẹ́ẹ̀méje sára ẹni tó fẹ́ wẹ ara rẹ̀ mọ́ kúrò nínú ẹ̀tẹ̀, kó sì kéde pé ẹni náà ti di mímọ́, kó sì tú ààyè ẹyẹ náà sílẹ̀ lórí pápá gbalasa.+
-