-
Léfítíkù 11:32, 33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 “‘Tí wọ́n bá kú, ohunkóhun tí wọ́n bá já bọ́ lé yóò di aláìmọ́, ì báà jẹ́ ohun èlò onígi, aṣọ, awọ tàbí aṣọ ọ̀fọ̀.* Kí ẹ ri ohun èlò èyíkéyìí tí ẹ bá lò bọnú omi, yóò sì di aláìmọ́ títí di alẹ́; lẹ́yìn náà, ó máa mọ́. 33 Tí wọ́n bá já bọ́ sínú ohun èlò tí wọ́n fi amọ̀ ṣe, kí ẹ fọ́ ọ túútúú, ohunkóhun tó bá sì wà nínú rẹ̀ yóò di aláìmọ́.+
-