Léfítíkù 15:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “‘Tí ẹ̀jẹ̀ bá ń dà jáde lára obìnrin kan, kó ṣì jẹ́ aláìmọ́ nínú ìdọ̀tí nǹkan oṣù rẹ̀ fún ọjọ́ méje.+ Ẹnikẹ́ni tó bá fara kàn án yóò jẹ́ aláìmọ́ títí di alẹ́.+
19 “‘Tí ẹ̀jẹ̀ bá ń dà jáde lára obìnrin kan, kó ṣì jẹ́ aláìmọ́ nínú ìdọ̀tí nǹkan oṣù rẹ̀ fún ọjọ́ méje.+ Ẹnikẹ́ni tó bá fara kàn án yóò jẹ́ aláìmọ́ títí di alẹ́.+