Hébérù 10:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Bákan náà, gbogbo àwọn àlùfáà máa ń lọ sẹ́nu iṣẹ́ wọn lójoojúmọ́ kí wọ́n lè ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́,*+ kí wọ́n sì lè rú àwọn ẹbọ kan náà léraléra,+ èyí tí kò lè mú ẹ̀ṣẹ̀ kúrò pátápátá.+
11 Bákan náà, gbogbo àwọn àlùfáà máa ń lọ sẹ́nu iṣẹ́ wọn lójoojúmọ́ kí wọ́n lè ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́,*+ kí wọ́n sì lè rú àwọn ẹbọ kan náà léraléra,+ èyí tí kò lè mú ẹ̀ṣẹ̀ kúrò pátápátá.+