-
Léfítíkù 16:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 “Kó ṣe ètùtù fún ibi mímọ́ torí ìwà àìmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti àṣìṣe wọn àti ẹ̀ṣẹ̀ wọn,+ bẹ́ẹ̀ náà ni kó ṣe fún àgọ́ ìpàdé, èyí tó wà láàárín wọn, láàárín àwọn tó ń hùwà àìmọ́.
-