ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 16:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Kí Áárónì ṣẹ́ kèké lórí ewúrẹ́ méjèèjì, kèké kan fún Jèhófà, kèké kejì fún Ásásélì.*

  • Léfítíkù 16:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Kí Áárónì gbé ọwọ́ rẹ̀ méjèèjì lé orí ààyè ewúrẹ́ náà, kó jẹ́wọ́ gbogbo àṣìṣe àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti gbogbo ìṣìnà wọn àti gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn sórí rẹ̀, kí ó kó o lé orí ewúrẹ́+ náà, kó wá yan ẹnì kan* tó máa rán ewúrẹ́ náà lọ sínú aginjù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́