10 Kí Áárónì máa ṣe ètùtù lórí àwọn ìwo rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan lọ́dún.+ Kí ó mú lára ẹ̀jẹ̀ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ti ètùtù+ láti ṣe ètùtù fún un lẹ́ẹ̀kan lọ́dún jálẹ̀ gbogbo ìran yín. Ohun mímọ́ jù lọ ló jẹ́ sí Jèhófà.”
7 àmọ́ àlùfáà àgbà nìkan ló máa ń wọ apá kejì lẹ́ẹ̀kan lọ́dún,+ kì í wọ ibẹ̀ láìsí ẹ̀jẹ̀,+ èyí tó fi máa ń rúbọ fún ara rẹ̀+ àti fún ẹ̀ṣẹ̀ táwọn èèyàn+ dá láìmọ̀ọ́mọ̀.