Léfítíkù 17:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí ẹ̀jẹ̀ ni ẹ̀mí* gbogbo onírúurú ẹran, torí pé ẹ̀mí* wà nínú ẹ̀jẹ̀ náà. Ìdí nìyẹn tí mo fi sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: “Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ̀jẹ̀ ẹran èyíkéyìí, torí ẹ̀jẹ̀ ni ẹ̀mí* gbogbo onírúurú ẹran. Kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá jẹ ẹ́.”+ Diutarónómì 12:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ṣáà ti pinnu pé o ò ní jẹ ẹ̀jẹ̀,+ má sì yẹ ìpinnu rẹ, torí pé ẹ̀jẹ̀ ni ẹ̀mí,*+ o ò sì gbọ́dọ̀ jẹ ẹ̀mí* pọ̀ mọ́ ẹran.
14 Torí ẹ̀jẹ̀ ni ẹ̀mí* gbogbo onírúurú ẹran, torí pé ẹ̀mí* wà nínú ẹ̀jẹ̀ náà. Ìdí nìyẹn tí mo fi sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: “Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹ̀jẹ̀ ẹran èyíkéyìí, torí ẹ̀jẹ̀ ni ẹ̀mí* gbogbo onírúurú ẹran. Kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá jẹ ẹ́.”+
23 Ṣáà ti pinnu pé o ò ní jẹ ẹ̀jẹ̀,+ má sì yẹ ìpinnu rẹ, torí pé ẹ̀jẹ̀ ni ẹ̀mí,*+ o ò sì gbọ́dọ̀ jẹ ẹ̀mí* pọ̀ mọ́ ẹran.