Ẹ́kísódù 22:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “Kí ẹ fi hàn pé èèyàn mi tó jẹ́ mímọ́ ni yín,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ jẹ ẹranko èyíkéyìí tí ẹranko búburú ti pa.+ Kí ẹ jù ú sí àwọn ajá. Diutarónómì 14:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ òkú ẹran èyíkéyìí.+ Ẹ lè fún àjèjì tó wà nínú àwọn ìlú* yín, kó sì jẹ ẹ́ tàbí kí ẹ tà á fún àjèjì. Torí pé èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín. “Ẹ ò gbọ́dọ̀ se ọmọ ewúrẹ́ nínú wàrà ìyá rẹ̀.+
31 “Kí ẹ fi hàn pé èèyàn mi tó jẹ́ mímọ́ ni yín,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ jẹ ẹranko èyíkéyìí tí ẹranko búburú ti pa.+ Kí ẹ jù ú sí àwọn ajá.
21 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ òkú ẹran èyíkéyìí.+ Ẹ lè fún àjèjì tó wà nínú àwọn ìlú* yín, kó sì jẹ ẹ́ tàbí kí ẹ tà á fún àjèjì. Torí pé èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín. “Ẹ ò gbọ́dọ̀ se ọmọ ewúrẹ́ nínú wàrà ìyá rẹ̀.+