17 “‘Tí ọkùnrin kan bá bá arábìnrin rẹ̀ tó jẹ́ ọmọ bàbá rẹ̀ tàbí ọmọ ìyá rẹ̀ lò pọ̀, tó rí ìhòòhò obìnrin náà, tí obìnrin náà sì rí ìhòòhò rẹ̀, ohun ìtìjú ni.+ Kí ẹ pa wọ́n níṣojú àwọn ọmọ àwọn èèyàn wọn. Ó ti dójú ti arábìnrin rẹ̀. Kó jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.