Léfítíkù 20:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ọkùnrin tó bá bá ìyàwó arákùnrin òbí rẹ̀ lò pọ̀ ti dójú ti* arákùnrin òbí rẹ̀.+ Kí wọ́n jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn. Kí wọ́n kú láìbímọ.
20 Ọkùnrin tó bá bá ìyàwó arákùnrin òbí rẹ̀ lò pọ̀ ti dójú ti* arákùnrin òbí rẹ̀.+ Kí wọ́n jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn. Kí wọ́n kú láìbímọ.